WAEC Yoruba Questions and Answers: We will gladly provide you with free access to previous WAEC Yoruba questions in this article. Along with many other exam-related data, you will comprehend how the WAEC Yoruba questions are structured. All you have to do is stay concentrated and adhere to my advice.

WAEC Yoruba Questions and Answers

The West African Senior School Certificate Examination, for University and Jamb admission examinations in West African nations, is conducted by the West African Examinations Council (WAEC). More than three million applicants applied for the WAEC-organized tests in a single year.

WAEC Yoruba Questions and Answers

SECTION A – AROKO:

1. (a) Ìdíje kan tí ó wáyé ni ilé-ẹ̀kọ́ mi.
(b) Ọ̀rẹ́ mi tí mo fẹ́ràn jù lọ.
(c) Ìsàlẹ̀ orọ̀ ní ẹ̀gbin.
(d) Ẹ̀sìn ti dòwò lórílẹ̀ èdè yìí.
(e) Ko lẹ́tà sí ọ̀rẹ́ ri tí ó wà ní ilẹ̀ òkèèèrè kí o sàlàyé  akitiyan ìjoba lórí iná ẹ̀létíírìkì ní orílẹ̀-èdè rii.

2. Sàlàyé ìhun ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn wúnrẹ̀n wọ̀nyí kí o sì fi àppeere méjì méjì gbe ìdáhùn rẹ̀ lẹ́sẹ̀:
(a) àrànmọ́wájú;
(b) àrànmẹ́yìn:
(c) àrànmọ́ aláìfòró.

3. (a) Kí ni fáwẹ̀lì?
(b) Ṣe àpèjúwe ọ̀kọ̀ọ̀kan àwọn fáwẹ̀lì wọ̀nyí:
[i], [Ԑ], [a], [o], [ũ], [ͻ̃].

4. (a) Da´ru´ku i`s?`ri´ ?`r?` ti a fala` si´ ni´nu´ ?`k?`?`kan a`w?n gbo´lo´hu`n w?`nyi´:
(i) E?ku`n pa eran.(ii) B?´la´ ri`n de´ ile´.
(ii) W?´n gba owo´ Ade´??la´.
(iii) O´ pupa fo`o`.
(iv) Aja´ gbe´ eegun.
(v) Mo fo aoo.
(b) Lo ?`k?`?`kan ?`r?` ti a fa`la` si´ ni ab?` (a) g?´g?´ bi´ ori´ ni´nu´ gbo´lo´hu`n a`ki´ye`si´ ala´t?num?´.

Read Also!!

SECTION B – LITIRESO:

5. Nínú ìtàn “Ìjàpá àti àwọn Ẹranko” ète wo ni Ìjàpá pa àti pé báwo ni àṣírí rẹ̀ ṣe tú?

6. Ṣalàyé ohun tí ifá so nipa Ògún.

7. Se àlàyé kikún nipa bi Ọ̀jẹ́làdé ti o di ọ̀nì ṣe di ènìyàn padà.

8. Ṣàlàyé lẹ́kùnrẹ́rẹ́ ohun tí ó ṣokùnfà kíkó jáde ìyá Ọlánikẹ̀ẹ́ nílé ọkọ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì.

9. Sàlàyé ìhùwàsí Ahun gẹ́gẹ́ bi akéwì ṣe fì yé wa nínú ewì náà.

10. sàlàyé bí Àbẹ̀ó ṣe ba ayé Àńwòó jẹ́.

SECTION C – ASA:

11. Dárúku oríṣì oúnje mẹ́fà tí a ń fi erèé/ẹ̀wà se kí o sì sàlàyé bí a tì ń se méjì nínú won.

12. Dárúko mẹ́fà nínú irinṣẹ́ àgbẹ̀de kí o sì sàlàyé sókí sókí lórí ọ̀kọ̀ọ̀kan.

DISCLAIMER! These are not real WAEC GCE Yoruba questions but likely repeated questions over the years to help candidates understand the nature of their examinations. Ensure to take note of every question provided on this page.

Checkout out other unique articles on our blog for more detailed information and do well to share with your friends and family. Follow us on our Twitter and Facebook to stay updated with premium information.